Friday, 5 January 2018

Nigerian praise and worship with tonic solfa

SPECIAL REQUEST FROM OLADAYO OLUWASEUN FOLAOLUWAPE ADURAH SNR
KO SU WA LATI MA KO ORIN TI IGBANI
KO SU WA LATI MA KO ORIN TI IGBANI
1. Ko su wa lati ma ko orin ti igbani(dmmmfsmrd, lls)
Ogo f’olorun Aleluya(dddds, mdrmr)
A le fi igbagbo korin na s’oke kikan(rdmmmfsmrd, lls)
Ogo f’olorun, Aleluya!(dddds, mdrd)

CHORUS
Omo olorun ni eto lati ma bu s’ayo(mfsssss, sslllls)
Pe ona yi nye wa si,(ssddtls)
Okan wa ns’aferi Re(sslsfmr)
Nigb’o se a o de afin Oba wa ologo,(sfmfmrd, sslllls)
Ogo f’olorun, Aleluya!(dddds, mdrd)

2. Awa mbe n’nu ibu ife t’o ra wa pada,(dmmmfsmrd, llls)
ogo f’olorun Aleluya!(dddds, mdrmr)
Awa y’o fi iye goke lo s’oke orun(dmmmfsmrd, llls)
Ogo f’olorun, Aleluya!(dddds mdrd)

3. Awa nlo si afin kan ti a fi wura ko,(dmmmfsmrd, llls)
ogo f’olorun Aleluya!(dddds, mdrmr)
Nibiti a ori Oba ogo n’nu ewa Re(dmmmfsmrd, llls)
Ogo f’olorun, Aleluya!(dddds, mdrd)

4. Nibe ao korin titun t’anu t’o da wa nde(dmmmfsmrd, llls)
Ogo f’olorun Aleluya!(dddds, mdrmr)
Nibe awon ayanfe yo korin ‚yin ti Krist; (dmmmfsmrd, llls)
Ogo f’olorun, Aleluya!. Amin(dddds, mdrd, lls)

No comments:

Post a Comment